ọmọdé

DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

RÍ GBOGBO Ẹ̀

Ìtọ́wò Fídíò Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà: Ṣé Jèhófà Máa Ń Dáhùn Àdúrà?

Wo fídíò yìí kó o lè rí bí Jèhófà ṣe dáhùn àdúrà Tósìn.

DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

RÍ GBOGBO Ẹ̀

Jèhófà Máa Ń Dárí Jini

Tá a bá ṣàṣìṣe, kí ló yẹ ká ṣe? Ẹ jẹ́ ká wo ohun tí Kọ́lá kọ́ nínú ìtàn Bíbélì kan.