Ohun Tuntun Wo Ló Wà ní JW.ORG?

2024-05-06

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Håkan Davidsson: A Kọ́wọ́ Ti Iṣẹ́ Tó Ń Mú Kí Òtítọ́ Bíbélì Gbilẹ̀

Iṣẹ́ ìsìn Jèhófà ni Håkan pinnu láti fayé ẹ̀ ṣe dípò kó máa “jayé kiri.” Lẹ́yìn àádọ́ta ọdún, ó ti fojú ara ẹ̀ rí bí Jèhófà ṣe ń jẹ́ kí ìhìn rere dé ọ̀dọ̀ gbogbo orílẹ̀-èdè àti ẹ̀yà àti ahọ́n.

2024-05-06

Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!

Ìgbà Wo Ni Gbogbo Ogun Yìí Máa Dópin?​—Kí Ni Bíbélì Sọ?

Láìpẹ́ kò ní sí ogun mọ́. Bíbélì sọ bó ṣe máa ṣẹlẹ̀.

2024-05-06

ÀKÓJỌ ÀPILẸ̀KỌ ÀTI FÍDÍÒ

Máa Ran Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́ Kó O Má Bàa Dá Wà​—Ohun Tí Bíbélì Sọ

Wo ọ̀nà méjì tó o lè gbà ṣe ara ẹ láǹfààní tó o bá ń ran àwọn míì lọ́wọ́.

2024-05-01

ILÉ ÌṢỌ́

Ìmọ̀ràn Tó Ṣeé Gbára Lé Nípa Ohun Tó Dáa àti Ohun Tí Kò Dáa

Ka ìwé yìí kó o lè mọ bó o ṣe lè ṣe ohun tó dáa táá sì ṣe ìwọ àti ìdílé rẹ láǹfààní lọ́jọ́ iwájú.

2024-04-16

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Jinlẹ̀ Kó O Lè Wà Lójúfò

2024-04-16

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé​—July 2024

Ta ni “obìnrin” tí Àìsáyà 60:1 sọ, báwo ló ṣe “dìde,” tó sì “tan ìmọ́lẹ̀”?

2024-04-16

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Bí Ara Ẹ Ṣe Lè Mọlé Nínú Ìjọ Tuntun

Ọ̀pọ̀ àwọn ará ló ti kó lọ sí ìjọ tuntun tára wọn sì mọlé níbẹ̀. Kí ló mú kí wọ́n ṣàṣeyọrí? Wo ìlànà mẹ́rìn tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ tó o bá kó lọ síjọ tuntun.

2024-04-16

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

July 2024

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti September 9–​October 6, 2024 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.