JÍ! January 2013 | Bó O Ṣe Lè Kọ́ Ọmọ Rẹ Níwà Ọmọlúwàbí Lóde Òní
Bá a ṣe lè yẹra fún àṣìṣe mẹ́ta tí àwọn òbí kan máa ń ṣe.
Ohun Tó Ń Lọ Láyé
Mọ àwọn ohun tó ń ṣẹlẹ̀ láyé.
ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ
Bó O Ṣe Lè Máa Bá Ọmọ Rẹ Tó Ti Ń Bàlágà Sọ̀rọ̀
Ṣé ó máa ń sú ẹ tó o bá ń bá ọmọ rẹ tó tí ń bàlágà sọ̀rọ̀? Kí ló máa ń mú kó nira gan-an?
ÌFỌ̀RỌ̀WÁNILẸ́NUWÒ
Onímọ̀ Sáyẹ́ǹsì Kan Ṣàlàyé Ohun Tó Gbà Gbọ́
Kọ́ nípa àwọn ẹ̀kọ́ sáyẹ̀ǹsì tó gbé yẹ̀wò àti ìdí tó fi gba Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run gbọ́.
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Bó O Ṣe Lè Kọ́ Ọmọ Rẹ Níwà Ọmọlúwàbí Lóde Òní
Ṣàyẹ̀wò kókó mẹ́ta tó lè ran àwọn ọmọ rẹ lọ́wọ́ láti máṣe níwà ìmọtara-ẹni-nìkan.
OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ
Párádísè
Ṣé ọ̀run ni Párádísè wà, àbí ibi gidi kan lórí ilẹ̀ ayé? Àwọn wo ló máa gbé níbẹ̀?
TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?
Bí Ẹyẹ Godwit Ṣe Ń Rìnrìn Àjò
Kà nípa ìrìn ààjò ọlọ́jọ́ mẹ́jọ ti ẹyẹ Godwit máa ń rìn. Ohun àgbàyanu gbáà ni.
Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì
Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Wọ́n Bá Ń Fi Ìṣekúṣe Lọ̀ Mí?
Kà nípa bí wọ́n ṣe máa ń fi ìṣekúṣe lọni àti ohun tó o lè ṣe tí wọ́n bá ń fi ìṣekúṣe lọ̀ ẹ́.
Sólómọ́nì Hùwà Ọlọgbọ́n
Wá ohun tó sọ nù nínú àwòrán yìí, so àmì tó-tò-tó pọ̀, kó o sì kùn ún.