ILÉ ÌṢỌ́ No. 1 2020 | Ibo La Ti Lè Rí Òtítọ́?

Bíbélì sọ ìdáhùn tó jóòótọ́ nípa àwọn ìbéèrè pàtàkì tá a máa ń béèrè.

Ibo La Ti Lè Rí Òtítọ́?

Nínú ayé tó kún fún ìsọfúnni tó ń ṣini lọ́nà yìí, kẹ́kọ̀ọ́ nípa ohun tó o lè ṣe láti wá ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè pàtàkì táwa èèyàn ń béèrè.

Òtítọ́ Ni Ọ̀rọ̀ Inú Bíbélì, Ó sì Ṣeé Gbára Lé

Jẹ́ kó dá ẹ lójú pé o lè gbára lé ohun tí Bíbélì sọ.

Ohun Tó Jẹ́ Òtítọ́ Nípa Ọlọ́run àti Kristi

Ìyàtọ̀ wo ló wà láàárín Jèhófà Ọlọ́run àti Jésù Kristi?

Ohun Tó Jẹ́ Òtítọ́ Nípa Ìjọba Ọlọ́run

Ìwé Mímọ́ jẹ́ ká mọ ẹni tó máa jẹ́ Ọba Ìjọba Ọlọ́run, ó tún sọ ibi tí ìjọba náà máa wà, ohun tó máa ṣe, àwọn tó máa ṣàkóso, àtàwọn ọmọ abẹ́ ìjọba náà.

Ohun Tó Jẹ́ Òtítọ́ Nípa Ọjọ́ Iwájú

Mú kí ìrètí tó o ní túbọ̀ dájú nípa ohun tí Ọlọ́run sọ pé ó máa ṣẹlẹ̀ sí ayé yìí àtàwọn tó máa gbé nínú rẹ̀ lọ́jọ́ iwájú.

Àǹfààní Tí Wàá Rí Tó O Bá Mọ Òtítọ́

Tó o bá mọ òtítọ́ nípa Ọlọ́run, wàá rí àǹfààní tó pọ̀.