Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ILÉ ÌṢỌ́ No. 2 2021 | Ayé Tuntun Ti Dé Tán!

Ṣé àwọn nǹkan tó ń ṣẹlẹ̀ láyé báyìí fi hàn pé òpin ayé ti dé tán? Tó bá rí bẹ́ẹ̀, kí la lè ṣe ká lè là á já nígbà tí òpin ayé bá dé? Kí ló máa ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn tí òpin ayé bá dé? Nínú ìwé yìí, Bíbélì máa dáhùn àwọn ìbéèrè yìí lọ́nà tó ń fini lọ́kàn balẹ̀.

 

Ayé Tuntun Là Ń Fẹ́!

Àwọn nǹkan tó ń ṣẹlẹ̀ láyé báyìí fi hàn pé aráyé ń fẹ́ àyípadà rere.

Ṣé Ayé Yìí Máa Pa Run Ni?

Bíbélì sọ pé òpin ayé ń bọ̀, bákan náà ó tún sọ pé títí láé làwọn èèyàn èèyàn á máa gbé ayé.

Ìgbà Wo Ni Jésù Sọ Pé Òpin Máa Dé?

Ṣé ò ń rí àwọn nǹkan tí Jésù sọ tẹ́lẹ̀ pé ó máa ṣẹlẹ̀?

Ohun Tó Yẹ Kó O Ṣe Tó O Bá Fẹ́ Gbé Inú Ayé Tuntun

Tá a bá jẹ́ ọ̀rẹ́ Ọlọ́run, báwo nìyẹn ṣe máa jẹ́ ká rí ìgbàlà?

Ayé Máa Tó Di Párádísè!

Tí Ọlọ́run bá mú àwọn ìlérí ẹ̀ ṣẹ, báwo ni ayé ṣe máa rí?

Ṣé Òpin Ayé Ti Dé Tán?

Ohun tí Bibélì sọ nípa òpin ayé lè yà ẹ́ lẹ́nu.