Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ẹ̀kọ́ Bíbélì

ỌMỌ ỌDÚN MẸ́TA ÀTI ÀWỌN TÍ KÒ TÓ BẸ́Ẹ̀

Ẹ̀kọ́ Bíbélì

Òjò ń rọ̀.

Táyọ̀ ń sunkún pé:

“Mi ò lè jáde.

Kí ló dé tí òjò yìí ò dá?”

Ṣùgbọ́n lójijì!

Oòrùn yọ.

Òjò sì dá.

Inú Táyọ̀ dùn!

Táyọ̀ sáré jáde, ó sì rí ohun kan tó yà á lẹ́nu.

Táyọ̀ sọ pé, “Mi ò mọ̀ pé òjò tí Ọlọ́run ń rọ̀ ni ó ń mú kí òdòdó dàgbà!”

IṢẸ́ ÒBÍ

Ní kí ọmọ rẹ tọ́ka sí:

  • Fèrèsé

  • Táyọ̀

  • Òdòdó

  • Ẹyẹ

  • Igi

Fara balẹ̀ wá àwọn nǹkan yìí.

  • Kòkòrò kan

  • Ọkọ̀ òfuurufú

Ka Ìṣe 14:17. Kí nìdí tí Jèhófà fi dá òjò?