Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÍ NI BÍBÉLÌ FI KỌ́NI GAN-AN?

Ìrìbọmi Ló Máa Fìdí Àjọṣe Rẹ Pẹ̀lú Ọlọ́run Múlẹ̀ (Apá 3)

Orí 18 ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé

Kí ni ìrìbọmi túmọ̀ sí? Ní ìbámu pẹ̀lú ohun tí Bíbélì sọ, kí ni Ọlọ́run fẹ́ kí ẹni tó ti ṣe ìyàsímímọ́ máa ṣe?