Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ÌWÉ ÀJÁKỌ

Jẹ́ Kí Ohun Tó ò Gbàgbọ́ Dá Ọ Lójú: Kéèyàn Ma Tíì Ní Ìbálòpọ̀ Rí | Ìwé Àjákọ fún Àwọn Ọ̀dọ́

Ìwé àjákọ tó máa mú kí ìpinnu tó o ṣe láti tẹ̀ lé òfin Ọlọ́run nípa ìbálòpọ̀ ṣáájú ìgbéyàwó túbọ̀ fẹsẹ̀ múlẹ̀.