Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

IBI TÍ MO KỌ ÈRÒ MI SÍ

Bó O Ṣe Lè Máa Fi Àyè Àṣìṣe Sílẹ̀

Ìwé yìí máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó o lè mọ bó ò ṣe ní máa retí ohun tó pọ̀ jù lọ́wọ́ ara ẹ àti lọ́wọ́ àwọn míì.