Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ẹ̀kọ́ 5: Jẹ́ Ká Lọ sí Òde Ẹ̀rí

Ẹ̀kọ́ 5: Jẹ́ Ká Lọ sí Òde Ẹ̀rí

Ṣé Tósìn ti múra tán láti lọ sí òde ẹ̀rí?

O Tún Lè Wo

ERÉ DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Ṣe Àpò Òde Ẹ̀rí Tìrẹ!

Kí ló yẹ́ kó o ní tí o bá fẹ́ lọ sí òde ẹ̀rí? Ẹ̀kọ́ yìí máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti mọ bí wàá ṣe ṣe àpò òde ẹ̀rí rẹ.

ERÉ DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Ge Iwe To Ni Aworan Lara Yii!

Maa fi sami si ibi to o kekoo de ninu awon iwe re!

Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ

Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé

Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.