Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ERÉ ALÁWÒRÁN

Kí Lá Rí Kọ́ Lára Nóà?

Wa eré yìí jáde kó o sì tẹ̀ ẹ́, ya àwòrán náà tán, kí ìwọ àti ìdílé rẹ jọ dáhùn àwọn ìbéèrè tó wà níbẹ̀.