Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÌKÀNNÌ JW.ORG

Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Máa Ń Béèrè​—JW.ORG

Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Máa Ń Béèrè​—JW.ORG

Àwọn browser tó lòde báyìí ń bá ìkànnì wa ṣiṣẹ́, àwọn bíi Chrome, Edge, Firefox àti Safari, ẹ sì lè lò ó lórí ẹ̀rọ Android, iOS, Mac àti Windows. Àwọn ẹ̀rọ tó ń lo Android 5.1 àtàwọn míì tó tuntun ju bẹ́ẹ̀ lọ sì lè lo ọ̀pọ̀ lára àwọn browser yìí.

Ká lè dáàbò bo ìkànnì jw.org, kí ọkàn àwọn tó ń lọ síbẹ̀ sì lè balẹ̀ nígbà tí wọ́n bá ń lò ó, ìkànnì náà lè má gba àwọn ẹ̀rọ tó ń lo àwọn browser àti operating system tó ti pẹ́ láyè láti wọ orí ìkànnì náà. Bí àpẹẹrẹ, ẹni tó bá ń lo Internet Explorer kò ní lè wọlé sórí ìkànnì náà. Látìgbàdégbà, àá máa sọ àwọn ohun tí ẹ̀rọ kan gbọ́dọ̀ ní kó tó lè wọ orí ìkànnì náà. Tó ò bá lè wọlé sórí ìkànnì náà tàbí tí oò bá lè ṣe àwọn nǹkan kan níbẹ̀, gbìyànjú láti wa ẹ̀dà tuntun browser tó ń lò sórí ẹ̀rọ rẹ, kó o sì tún fi ẹ̀dà tuntun operating system ẹ̀rọ re sórí ẹ̀rọ rẹ. Tí browser tó bá ẹ̀rọ rẹ wá kò bá ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ìkànnì náà, gbìyànjú láti wa tuntun míì tó jẹ́ ìgbàlódé sórí ẹ̀rọ rẹ.

 

Ọ̀rẹ́ rẹ kan tó mọ̀ nípa ìkànnì jw.org lè ràn ẹ́ lọ́wọ́. Tíyẹn ò bá ṣeé ṣe, jọ̀ọ́ kàn sí ẹ̀ka ọ́fíìsì wa tó sún mọ́ ẹ jù.