Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ABALA ÀWỌN Ọ̀DỌ́

Bí O Ṣe Lè Rí Àwọn Ọ̀rẹ́ Tó Jẹ́ Adúróṣinṣin

Kẹ́kọ̀ọ́ látinú àpẹẹrẹ Jónátánì àti Dáfídì. Wa ẹ̀kọ́ yìí jáde, ka ìtàn Bíbélì tó wà níbẹ̀, kó o sì máa fojú inú wò ó bí ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́!