Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Sri Lanka

 

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Orílẹ̀-èdè Siri Láńkà

  • Iye àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà​—7,003

  • Iye àwọn ìjọ​—98

  • Iye àwọn tó wá síbi Ìrántí Ikú Kristi​—15,721

  • Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún​—3,195

  • Iye èèyàn​—22,181,000

2019-01-15

SRI LANKA

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ṣe Àkànṣe Àpéjọ Fúngbà Àkọ́kọ́ ní Siri Láńkà

Ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ló wá láti orílẹ̀-èdè méje ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ láti wá bá àwọn ará wọn lọ́kùnrin lóbìnrin nílùú Colombo ṣe àkànṣe àpéjọ. Ìgbà àkọ́kọ́ tírú ẹ̀ máa wáyé nìyẹn ní Siri Láńkà.

2016-10-05

SRI LANKA

Àwọn Ẹlẹ́rìí Ṣèrànwọ́ Lẹ́yìn Omíyalé Tó Ṣẹlẹ̀ ní Siri Láńkà

Ohun tó ṣẹlẹ̀ ní Siri Láńkà yìí ló tíì burú jù láti ohun tó tó ọdún méjìlá sẹ́yìn. Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà sì ṣètò ìrànwọ́ nígbà tó ṣẹlẹ̀.